To
Ise logun ise
Mura sise ore mi
Ise lafi di eni giga
Bi.a ko bare ni feyin ti
Bi ole lari
Bi a ko ba reni gbekele
A te ra Mo ise eni
Iya re Le lowo lowo
Baba re Le lesin lekan
To ba gboju lewon
O te tan ni Mo so fun o
Ohun ti a ba sise fun ki le pelowo
Ohun ta ba fara sise fun ni pe lowo eni
Apa Lara igunpa ni ye kan.
Ti aye ba nfe loni
Toba lowo lowo
Aye ama Fe Lola
Ti o ba wa nipo atata
Aye a ye o si terin terin
Kodeni TI rago Kiri ko ri bi
Aye TI yinmu sio
Eko si tun soni doga
Mura ki o ko daradara
Iya nbe fomo ti ko gbon
Ekun nbe fomo
Ti nsare Kiri
Mo fowuro sere ore mi
Mura sise ojo nlo.


From
To
Load comments
Everything about this group should be in Yoruba language but other languages are welcome too.

Screenshot

From
To
Load comments

| | | | | | Statistics | Advertise | About | Terms | Privacy